Simple verbsYoruba words

Yé
to survive
Kán
to affect / break / injure
gbin
to plant
túmọ̀
to interpret
ṣàlàyé
to explain
Potentially could be split
tó
to be up to certain amount / worthy
bàtà ẹni tí emi kò tó gbé
nà
to beat (violence)
ná
to engage/ haggle with
Nù
to be lost
kọjá
to pass (a position or object)
dì
to pack / hold / tie
di
to become
dá
to pack (tie something )
da
pour
pá
kill
Pààrò
Exchange
paré
to cancel
ṣẹ́gun
conquer
lù
hit
wáyé
to occur / take place
gbà
to take / accept
já
to lead
já sí ayọ̀
Ṣèdájú
to confirm / certainly
rú
to break / violate
Rérìn
to laugh
fẹ̀
wide
dà
to be evident / where?
ẹ̀gbọ́n ẹ dà?
wú
to swell
fà
pull / drag
má fà mi ní ereke (dont pull my cheek)
kán
broken
ó kán ní apá (he broke his arm)
gé
cut
Ìka ẹsẹ̀ rẹ̀ kan tí gè
jogún
inherit
sunmọ
to be close
Níbo ni ilé elegbogi ti ó sunmọ jùlọ wa
pè
to call
Pè ọkọ̀ aláìsàn pè mi
yawo
borrow
Ṣé Mo lè yawo ...?
Yé
understand
emi kò lóye kò yé mi
sínsin
burying (present participle)
sínsin òkú àwọn ọ̀ba tí ìjọba ṣẹ̀ṣẹ̀ gbé jáde
ṣe àṣàrò
meditate
ó ń ṣe àṣàrò ní ọ̀sán ati ní òru
dabi
like (to be like)
wọn dabi iyangbo ti afẹ́fẹ́ ń fẹ́ lọ
ṣègbé
perish
ro
hurt / ache
gbogbo ara ń ro mí
fọ́
break
orí ń fọ́ ọ orí fifọ́ ni
dùn
ache / hurt / happy
gbogbo ara ń dun màmá mi àyà dídùn ni inú mi dùn
run
to turn over
inú ń rún un
lo
use
lo òògùn kan lẹ́ẹ̀mẹ́rin lọ́jọ́ kan
bọ̀
take off / coming
bọ̀ ṣẹ́ẹ́ti rẹ ẹnikan ti ó pọ̀ jú mi lọ ń bọ̀ lẹ́yìn mi
sé
hold
sé èémí rẹ (hold your breath)
gbé
move / live / carry
gbé ẹsẹ̀ rẹ gbé ọwọ́ rẹ sókè
kí
visit / greet
lè
can/ be able to
rí
find / see
wà
to be
wá
come
ní
in / at / have (possess) / say
jó
dance
dìde
stand up
dákẹ́
keep quiet
sùn
sleep
dé
to arrive / reach / return / cover
nígbàwo lẹ délé? kí nìdí to fi pẹ́ délé? ba mi dé ìkòkò yẹn
jí
wake up
jẹun
eat
burú
bad
bínú
upset
ma bínú inú ń bí mi
gbọ́
hear
bọ́
to escape / feed
mo bọ́ lọ́wọ́ ogun, wahala àti àìní ìtẹ̀síwájú bísí bọ́ ẹran tà a
tẹ̀dó
built/ settled
ìlú ti a tẹ̀dó lórí òkè kò lè farasin
tú
to loose / untie / release
Ọlọ́run tú ẹ̀mí mímọ́ sórí ìjọ Kristẹni
kìlọ
to warn
bi Ọlọ́run ti kìlọ fún wọn lójú àlá pe, ki wọn ki o má ṣe padà tọ̀ herodu lọ mọ̀
sálọ
run away
ki o sálọ sí egipti
bínú
get angry
ó bínú
ranṣẹ
send
Mo kàwé náà, mo sì ń fi awọn ìbéèrè ranṣẹ si ọ ki o lè dáhùn wọn ninu awọn lẹta rẹ.
sunkún
to cry / weep for
Rákélì ń sunkún awọn ọmọ rẹ̀
bẹ̀rù
afraid
ó bẹ̀rù lati lọ síbẹ̀
jẹ́wọ́
confess / acknowledge
Wọ́n ń jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ wọn
mọ̀
know
inú mi dún lati mọ̀ ẹ
lé
upon
ẹ̀mí Ọlọ́run sọkalẹ bi àdàbà, ó si bà lé e
pàṣẹ
order
pàṣẹ ki òkúta wọ̀nyí di àkàrà
kọ̀wé
to write
A ti kọ̀wé rẹ̀
wín
borrow
lọ́dọ̀ ẹni tó ń fẹ́ wín lọ́wọ́ rẹ
mú
cause / make / bring/ drink
nítorí tí ó ń mú oòrùn rẹ̀ ràn sára ènìyàn
pé
perfect
nítorí náà ki ẹ̀yin ki ó pé, bi Baba yín ti ń bẹ lọrun ti pé
súre
bless
Ọlọrun sì súre fun wọn
ṣoore
to be kind / show kindness to / help
ẹni tó ń ṣoore ń ṣe ara rẹ̀ láǹfààní Jésù ṣoore fún àwọn aláìní
jalè
to steal
níbi tí awọn olè í rúnlẹ̀ ti wọn si í jalè
mọ́
clean
bi ojú rẹ ba mọ́, gbogbo ará rẹ ni yóò kún fun imọlẹ
sìn
worship/ serve
kò si ẹni tó lè sìn Olúwa meji
fẹ́ràn
like
wẹ̀
take a bath
kórè
harvest / reap
fúnrúgbìn
sow
dàgbà
grow / raised / nurture
rànwú
spin
Tète
to correct
sáré
run
jókòó
sit down
sọ̀rọ̀
to talk / speak
pariwo
shout / make noise
ṣe
do
kọrin
sing
dára
good
dárúkọ
to name
dín
to be less
rà
buy
kà
read
tóbi
big
ga
tall
sanra
fat
kúrú
short
jẹ́
is
kúnlé jẹ́ ènìyàn gíga
kéré
small
gbàgbé
forget
gbàgbọ́
believe
níwà jẹ́jẹ́
to be gentle
Wọ́n sì níwà jẹ́ ẹ́
Wọ́n
expensive
ọkọ̀ rẹ̀ kéré, ó sì Wọ́n
jẹ́ olóòótọ̀
to be honest
ọkọ rẹ̀ jẹ́ olóòótọ̀
jẹ́ aláàánú
to be merciful / caring
ó jẹ́ aláàánú
simi
rest
mo fẹ́ lọ simi
ṣàkíyèsí
notice
a ṣàkíyèsí yín
ráyè
to have opportunity
nígbà wo lo máa ráyè wo ẹ̀rọ yìí
ṣe aláìní
do without
n kò lè ṣe aláìní fóònù
wo/wò
to watch
gbààwẹ̀
fasting
mi o fẹ́ gbààwẹ̀ lónìí
rọrùn
easy
fúyẹ́
small / light (weight)
fò
fly/ jump
fọ
wash
kọ́
first / build / teach
jẹ́ kí n ki o kọ́ lọ ìsìnkú baba mi ná
yọrí sí
to lead to / result in
kéde
to declare /announce
ṣèṣekúṣe
to commit adultery
wọmi
to become worthless / devastated
pin
share /end/ divide
yẹ
to be worthy/ proper
ṣó yẹ kí n ṣèrìbọmi
gbọ́n
wise
Tọ̀
to follow
Wọ́n ti ìlú wọn rìn tọ̀ ọ́ pẹlu ẹsẹ̀
sẹ́
deny
ṣubú
to fall
wọlé
to come / go in, resume , come into power
Ọba wá sọ pé: “Ẹ jẹ́ kó wọlé." àwọn akẹ́kọ̀ọ́ máà tó wọlé ta ló wọlé nínú ìdìbò náà
sébọ́
to become unreceptive
yà
to seperate / become
ó yà wọn lẹ́nu ó ti yà alágídí
fi...pamọ́ (delete)
to save / hide
pàdé
to meet, met, meeting
Ṣó ti pàdé ọ̀rẹ́ mi? Ṣá lè pàdé lónìí? Ṣá ní láti pàdé lónìí? Ṣe ẹ má a pàdé mi ńlé?
kórira
to hate
ṣetán
ready / finish
ó yẹ ka ti ṣetán
jìnà
far away
rán
send
ṣé mo lè rán yín
ní láti
to need / have to
bèrè lọ́wọ́
ask someone
Jẹ̀ka
to bite/eat your fingernails
ṣé o mọ̀ ọkùnrin tó ma ń Jẹ̀ka yẹn?
mùka
to suck your finger
ṣé ọmọ yín ma ń mùka? kò kí ń mùka kò da fún àgbàlagbà láti ma mùka
tàka
to tap your finger
ṣé obri, ó tàka sími? èmi lò ń tàka sí mo tàka òṣì dànù
nàka
to point at something/someone
ṣé ó nàka sí ẹ?
tọ́ka
to describe / refer to - something
ṣé o lè tọ́ka síbi tí mo ti lè rí oúnjẹ ní kent? ṣé ẹ ń tọ́ka sí mi?
dábá
to suggest
mo fẹ́ dábá pé ki a lọ
kọ
reject
ṣé ó kọ àbá yẹn ni
gbádùn
to enjoy/ to be well / sane / healthy
ṣé o gbádùn ara ẹ? ṣé o ń gbádùn ṣé o gbádùn mi ò gbádùn ara mi lànà
jẹ̀gbádùn
to enjoy
ṣé o jẹ̀gbádùn ara ẹ?
ṣiṣẹ́
to do work / working / worked
mo ń ṣíṣẹ́ pẹ̀lú ìjọba
jẹ
to eat / eating / eaten / ate
jẹ owó
to hit jackpot/ owe someone money
mo máa jẹ owó ẹ Ó jowó Kunle jẹ mi lówó
jẹ...gbèsè
to owe...money / be in debt
ṣé o jẹ lekan ní gbèsè o jẹ gbèsè
Jẹ̀yà / jìyà
to suffer
o máa jẹ̀yà má jẹ̀yà o! kí nìdí tí o fi n jẹ̀yà? o ò ní láti jẹ̀yà nítorí o jẹ gbèsè
jẹgba
to be flogged / make someone suffer
o má a jẹ ẹgba o máa jẹgba lọ́wọ́ mi
jẹunlọ
to exceed expectations
ó ti jẹunlọ
jẹ ojú
to dissapoint / deal with
mo má a jojú lekan mo máa jẹ ojú ẹ
jẹ ọrọ̀
to be in wealth / affleunce
eni tí ò jìyà kò lè jẹ ọrọ̀
jẹ èrè
to make profit
o má a ṣe òwò o má a jèrè
jẹ oba
to become king
ta ló jọba ìlú yín mi ò lè jọba
jẹ oyè
to become chief / title holder
mo fẹ́ joyè ṣó ti joyè ni?
jẹ dòdò
to admore someone / something
mo jẹdòdò aṣọ ẹ mo jẹdòdò ọ̀rẹ́ ẹ
jẹ ẹ̀bùn
to win a gift
mo jẹ̀bùn kan lánàá
jẹ ayé
to enjoy/chop life
mo má a jayé orí mi
jẹ ẹnu
to mutter words / speak in undertones
Jẹ̀jẹkújẹ
to eat nonsense / rubbish
o má a ń jẹ̀jẹkújẹ gan
jẹ gàba
to dominate / to have dominion
o ò lè jẹ gàba lé mi lórí
jẹ̀bi
to be guilty
má bínú mo jẹ̀bi o ò mọ̀ pe o jẹ̀bi?
jẹ àre
to be innocent / vindicated
mo jàre
jẹ ìrora
to be in pain
mo jẹ̀rora
jẹ oró
to be in deep pain / agony
Ó ń joró ikú
jẹ owú
to be jealous of so /smt
mo jowú ò ń jowú mi má jowú mi
káàbámọ̀
to regret
Ṣo káàbámọ̀ nǹkan to ṣé? Ṣé wọ́n káàbámọ̀ nnkan ti wọ́n ṣe? wọ́n kò káàbámọ̀ nǹkan tán ṣe
kùnà
to fail
rò
to think
kò rò pé ó ṣeéṣé
jàde
to go out
bọ́ síta
get out
bọ́ọta
kúrò
to leave
nígbàwo lo fẹ́ kúrò? mo máa kúrò lọ́lá mo fẹ́ tètè kúrò
gbìmọ̀
to plot
àwọn olórí àlùfáà gbìmọ̀ si Jésù lati pa á
jẹ́rìí
to bear witness
iwọ kò gbọ́ ohun ti wọ́n ń jẹ́rìí si ọ?
sùn wọra
to sleep deep
jarunpá
to sleep wild
falala
to drool
rẹjú
to take a nap
sùn díẹ̀
to sleep a little / take a nap
sùn lọ
to sleep off
yán
to yawn
hanrun
to snore
lálá
to dream
se ouńjẹ
to cook food
dáná ouńjẹ
to cook food
gbọ́ ouńjẹ
to cook food
roúnjẹ
to buy food
ta ouńjẹ
to sell food
jẹun lásìkò
to eat on time
ta
to be spicy
mi ò fẹ́ jẹ ouńjẹ yẹn nítorí ó ta gan
sàn
watery
mi ò fẹ́ jẹ ẹ̀wà tó sàn
yó
to be filled / satisfied
ṣé ó ti yó?
jẹun níta
to eat out
jeun si
eat more
padà wá
come back
mo máà padà wá mo padà wá sílé
padà sí
to return / go back to
ẹ padà sílé
kan lẹ̀kùn
to knock the door
ṣí
to open
tì
to lock / rest / relax
ti ilẹ̀kùn ti fèrèsé fi ẹ̀yìn tì
tà
to sell
rìn
to walk
jagun
to battle / fight a war
gbálẹ̀
to sweep the floor
pọnmi
to fetch water
kọ́lé
to build a house
ja
to fight
lùwẹ̀
to swim
là
to break
làágùn
to perspire / sweat
mo ń làágùn Wọ́n kò fẹ́ làágùn
pàdánù
to lose
ẹni tí ò ni á pàdánù
wárí
to tremble / come reverently
mo wárí fọ́ba tó ni dída ayé
foríbalẹ̀
to bow down
awa wá lati foríbalẹ̀ fun un
ya
to turn into (become)
mi ò fẹ́ ya aláìní
bẹ̀rẹ̀
to start / begin
nígbàwo lẹ fẹ́ bẹ̀rẹ̀?
fẹ̀yìntì
to retire
nígbà wo ni ìfẹ̀yìntì ẹ? wọn fẹ́ fẹ̀yìntì ní ọdún yìí mi ò fẹ́ kí o fẹ̀yìntì báyìí
gbéraga
to be proud / glorify oneself
pín
to share
pínyà
to separate
mi ò fẹ́ kẹ pínyà
gbìyànjú
to try
ṣakitiyan
to make an effort
dánnu
to brag / boast
dárin
to sing
gberin
to sing a song
pàtẹ̀wọ́
to applaude (clap)
juwọ́
to wave / let go
pẹnudé
to close mouth / keep secret
jò
to leak
To start learning, sign up for free.